English
​
My name is Oluwayemisi Olasele from Nigeria and a mom of three handsome children. I am a certified teacher of 5years teaching experience in English, writing skill, mentoring, child care.
I have a certification in (PGDE) Post Graduate Diploma In Education from National Teacher's Institute, Nigeria and also (TEFL) Teaching English as a Foreign Language course.
My native language is Yoruba and love teaching Yoruba as well. I am of the opinion that 'An investment in knowledge pays the best interest'. I love teaching, it allows me impact knowledge with the opportunity to see and experience a high retention of what my students have been taught.
I enjoy being a trustful resource and my skills in teaching has been a spontaneous adventure portraying, that teaching is delightful. This is to say - my classes are always exciting, engaging and productive.
​
Yoruba
Oruko mi ni Oluwayemisi Olasele lati orile ede Nigeria ti mo si je iya omo to re wa meta.
Mo ni iwe eri olukoni pelu iriri odun marun ni eko ede geesi, Kiko, bi won ti mo ju to ati itoju awon omo kekeke.
Mo ni iwe eri giga (PGDE) ni imo eko la ti Ile iwe giga ti olukoni ni orile ede Nigeria ati Kiko ede geesi gegebi eko okeere (TEFL).
Ede abinibi mi ni Yoruba, mo si nife si lati ko yin ni ede Yoruba bakanna. Amoran mi ni wipe 'nini owo si imon, maa ni ere ti o daara'
Mo ma ngbadun eri ti o se fi okan tan ati ebun mi ninu kikoni je ohun ti mo n gbadun lore koore, ti o fihan wipe kikoni daara.
Ti yin ni tooto